Home / Signos

Signos

De la A–Z De las Madres a los Niños

Ìdin Iwinlará (Òdí-Ogbè) Awo kéré awo òní Awo dàgbà awo ọ̀la Ọ̀gẹ̀dẹ̀ níí gbódò şọşìn şọrà, awo Ọlámèní-mọ̀la Díá fún Òní lojú pọ́n mi mọ Tíí şọmọ bíbí Àgbọnìrègún Ó fẹ̀yìntì ńfẹkún sùnráhùn ire gbogbo Ẹbọ ni wọ́n ní ó wáá şe Ó gbẹ́bọ ó rúbọ Njẹ, òní lojú pọ́n …

Read More »